Yorùbá Bibeli

Joh 4:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin kò ha nwipe, O kù oṣù mẹrin, ikorè yio si de? wo o, mo wi fun nyin, Ẹ gbé oju nyin soke, ki ẹ si wó oko; nitoriti nwọn ti funfun fun ikore na.

Joh 4

Joh 4:30-39