Yorùbá Bibeli

Joh 4:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lori eyi li awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ de, ẹnu si yà wọn, pe o mba obinrin sọ̀rọ: ṣugbọn kò si ẹnikan ti o wipe, Kini iwọ nwá? tabi, Ẽṣe ti iwọ fi mba a sọ̀rọ?

Joh 4

Joh 4:26-37