Yorùbá Bibeli

Joh 20:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu wi fun u pe, nitoriti iwọ ri mi ni iwọ ṣe gbagbọ́: alabukun-fun li awọn ti kò ri, ti nwọn si gbagbọ́.

Joh 20

Joh 20:25-31