Yorùbá Bibeli

Joh 20:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin ijọ mẹjọ awọn ọmọ-ẹhin si tún wà ninu ile, ati Tomasi pẹlu wọn: nigbati a si ti tì ilẹkun, Jesu de, o si duro larin, o si wipe, Alafia fun nyin.

Joh 20

Joh 20:24-31