Yorùbá Bibeli

Joh 20:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu wi fun u pe, Obinrin yi, ẽṣe ti iwọ fi nsọkun? tani iwọ nwá? On ṣebi oluṣọgba ni iṣe, o wi fun u pe, Alàgba, bi iwọ ba ti gbé e kuro nihin, sọ ibiti o gbé tẹ ẹ si fun mi, emi o si gbé e kuro.

Joh 20

Joh 20:9-19