Yorùbá Bibeli

Joh 20:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wi fun u pe, Obinrin yi, ẽṣe ti iwọ fi nsọkun? O si wi fun wọn pe, Nitoriti nwọn ti gbé Oluwa mi, emi kò si mọ̀ ibiti nwọn gbé tẹ́ ẹ si.

Joh 20

Joh 20:12-20