Yorùbá Bibeli

Joh 20:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

LI ọjọ ikini ọ̀sẹ ni kùtùkùtù nigbati ilẹ kò ti imọ́, ni Maria Magdalene wá si ibojì, o si ri pe, a ti gbé okuta kuro li ẹnu ibojì.

Joh 20

Joh 20:1-7