Yorùbá Bibeli

Joh 18:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si da a lohùn wipe, Jesu ti Nasareti. Jesu si wi fun wọn pe, Emi niyi. Ati Judasi pẹlu, ẹniti o fi i hàn, duro pẹlu wọn.

Joh 18

Joh 18:1-14