Yorùbá Bibeli

Joh 18:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina Pilatu wi fun wọn pe, Ẹ mu u tikaranyin, ki ẹ si ṣe idajọ rẹ̀ gẹgẹ bi ofin nyin. Nitorina li awọn Ju wi fun u pe, Kò tọ́ fun wa lati pa ẹnikẹni:

Joh 18

Joh 18:23-40