Yorùbá Bibeli

Joh 18:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu da a lohùn wipe, Emi ti sọ̀rọ ni gbangba fun araiye; nigbagbogbo li emi nkọ́ni ninu sinagogu, ati ni tẹmpili nibiti gbogbo awọn Ju npejọ si: emi kò si sọ ohun kan ni ìkọkọ.

Joh 18

Joh 18:18-25