Yorùbá Bibeli

Joh 18:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Peteru duro li ẹnu-ọ̀na lode. Nigbana li ọmọ-ẹhin miran nì, ti iṣe ẹni mimọ̀ fun olori alufa, o jade lọ, o si ba oluṣọna na sọ ọ, o si mu Peteru wọle.

Joh 18

Joh 18:7-20