Yorùbá Bibeli

Joh 18:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Simoni Peteru ẹniti o ni idà, o fà a yọ, o si ṣá ọmọ-ọdọ olori alufa, o si ke etí ọtun rẹ̀ sọnù. Orukọ iranṣẹ na ama jẹ Malku.

Joh 18

Joh 18:1-16