Yorùbá Bibeli

Joh 18:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBATI Jesu si ti sọ nkan wọnyi tan, o jade pẹlu awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ lọ soke odò Kedroni, nibiti agbala kan wà, ninu eyi ti o wọ̀, on ati awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀.

Joh 18

Joh 18:1-10