Yorùbá Bibeli

Joh 16:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nkan wọnyi ni mo ti sọ fun nyin tẹlẹ̀, ki ẹnyin ki o le ni alafia ninu mi. Ninu aiye, ẹnyin o ni ipọnju; ṣugbọn ẹ tújuka; mo ti ṣẹgun aiye.

Joh 16

Joh 16:32-33