Yorùbá Bibeli

Joh 16:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lõtọ, lõtọ ni mo wi fun nyin pe, Ẹnyin o ma sọkun ẹ o si ma pohùnrere ẹkún, ṣugbọn awọn araiye yio ma yọ̀: inu nyin yio si bajẹ, ṣugbọn ibinujẹ nyin li yio si di ayọ̀.

Joh 16

Joh 16:13-27