Yorùbá Bibeli

Joh 15:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ẹnyin ba ngbé inu mi, ti ọ̀rọ mi ba si ngbé inu nyin, ẹ ó bère ohunkohun ti ẹ ba fẹ, a o si ṣe e fun nyin.

Joh 15

Joh 15:1-10