Yorùbá Bibeli

Joh 15:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ibaṣepe emi kò ti ṣe iṣẹ wọnni larin wọn, ti ẹlomiran kò ṣe ri, nwọn kì ba ti li ẹ̀ṣẹ: ṣugbọn nisisiyi nwọn ti ri, nwọn si korira ati emi ati Baba mi.

Joh 15

Joh 15:20-27