Yorùbá Bibeli

Joh 14:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Olutunu na, Ẹmí Mimọ́, ẹniti Baba yio rán li orukọ mi, on ni yio kọ́ nyin li ohun gbogbo, yio si rán nyin leti ohun gbogbo ti mo ti sọ fun nyin.

Joh 14

Joh 14:16-31