Yorùbá Bibeli

Joh 14:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu dahùn o si wi fun u pe, Bi ẹnikan ba fẹràn mi, yio pa ọ̀rọ mi mọ́: Baba mi yio si fẹran rẹ̀, awa o si tọ̀ ọ wá, a o si ṣe ibugbe wa pẹlu rẹ̀.

Joh 14

Joh 14:17-31