Yorùbá Bibeli

Joh 14:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigba diẹ si i, aiye ki ó si ri mi mọ́; ṣugbọn ẹnyin ó ri mi: nitoriti emi wà lãye, ẹnyin ó wà lãye pẹlu.

Joh 14

Joh 14:10-23