Yorùbá Bibeli

Joh 14:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ani Ẹmí otitọ nì; ẹniti araiye kò le gbà, nitoriti kò ri i, bẹ̃ni kò si mọ̀ ọ: ṣugbọn ẹnyin mọ̀ ọ; nitoriti o mba nyin gbe, yio si wà ninu nyin.

Joh 14

Joh 14:12-23