Yorùbá Bibeli

Joh 14:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ kò ha gbagbọ́ pe, Emi wà ninu Baba, ati pe Baba wà ninu mi? ọ̀rọ ti emi nsọ fun nyin, emi kò da a sọ; ṣugbọn Baba ti ngbé inu mi, on ni nṣe iṣẹ rẹ̀.

Joh 14

Joh 14:1-18