Yorùbá Bibeli

Joh 13:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu da a lohùn wipe, Iwọ o ha fi ẹmí rẹ lelẹ nitori mi? Lõtọ, lõtọ ni mo wi fun ọ, Akukọ kì yio kọ, ki iwọ ki o to sẹ́ mi nigba mẹta.

Joh 13

Joh 13:31-38