Yorùbá Bibeli

Joh 13:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kì iṣe ti gbogbo nyin ni mo nsọ: emi mọ̀ awọn ti mo yàn: ṣugbọn ki iwe-mimọ́ ki o le ṣẹ, Ẹniti mba mi jẹun pọ̀ si gbé gigĩsẹ rẹ̀ si mi.

Joh 13

Joh 13:16-24