Yorùbá Bibeli

Joh 11:49 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Kaiafa, ọkan ninu wọn, ẹniti iṣe olori alufa li ọdún na, o wi fun wọn pe, Ẹnyin kò mọ̀ ohunkohun rara.

Joh 11

Joh 11:47-57