Yorùbá Bibeli

Joh 11:41 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni nwọn gbé okuta na kuro nibiti a gbe tẹ́ okú na si. Jesu si gbé oju rẹ̀ soke, o si wipe, Baba, mo dupẹ lọwọ rẹ, nitoriti iwọ gbọ́ ti emi.

Joh 11

Joh 11:32-44