Yorùbá Bibeli

Joh 11:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu wipe, Ẹ gbé okuta na kuro. Marta, arabinrin ẹniti o kú na wi fun u pe, Oluwa, o ti nrùn nisisiyi: nitoripe o di ijọ mẹrin ti o ti kú.

Joh 11

Joh 11:36-43