Yorùbá Bibeli

Joh 11:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina awọn Ju ti o wà lọdọ rẹ̀ ninu ile, ti nwọn ntù u ninu, nigbati nwọn ri ti Maria dide kánkan, ti o si jade, nwọn tẹ̀le e, nwọn ṣebi o nlọ si ibojì lọ isọkun nibẹ̀.

Joh 11

Joh 11:29-39