Yorùbá Bibeli

Joel 2:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o sure siwa sẹhin ni ilu: nwọn o sure lori odi, nwọn o gùn ori ile; nwọn o gbà oju fèrese wọ̀ inu ile bi olè.

Joel 2

Joel 2:4-13