Yorùbá Bibeli

Joel 2:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o sare bi awọn alagbara; nwọn o gùn odi bi ọkunrin ologun; olukuluku wọn o si rìn lọ li ọ̀na rẹ̀, nwọn kì yio si bà ọ̀wọ́ wọn jẹ.

Joel 2

Joel 2:1-12