Yorùbá Bibeli

Joel 2:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe ẹnikẹni ti o ba ke pè orukọ Oluwa li a o gbàla: nitori li oke Sioni ati ni Jerusalemu ni igbàla yio gbe wà, bi Oluwa ti wi, ati ninu awọn iyokù ti Oluwa yio pè.

Joel 2

Joel 2:27-32