Yorùbá Bibeli

Joel 2:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin o si mọ̀ pe, emi wà lãrin Israeli, ati pe: Emi li Oluwa Ọlọrun nyin, kì iṣe ẹlomiràn: oju kì yio si tì awọn enia mi lai.

Joel 2

Joel 2:25-31