Yorùbá Bibeli

Joṣ 9:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi, kiyesi i, li ọwọ́ rẹ li awa wà: bi o ti dara si ati bi o ti tọ́ si li oju rẹ lati ṣe wa, ni ki iwọ ki o ṣe.

Joṣ 9

Joṣ 9:17-27