Yorùbá Bibeli

Joṣ 9:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ìgo-awọ waini wọnyi, ti awa kún, titun ni nwọn; kiyesi i, nwọn fàya: ati ẹ̀wu wa wọnyi ati bàta wa di gbigbo nitori ọ̀na ti o jìn jù.

Joṣ 9

Joṣ 9:7-22