Yorùbá Bibeli

Joṣ 9:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ohun gbogbo ti o ṣe si awọn ọba awọn Amori meji, ti mbẹ ni òke Jordani, si Sihoni ọba Heṣboni, ati si Ogu ọba Baṣani, ti mbẹ ni Aṣtarotu.

Joṣ 9

Joṣ 9:3-13