Yorùbá Bibeli

Joṣ 8:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ti ara keji si yọ si wọn lati ilu na wá; bẹ̃ni nwọn wà li agbedemeji Israeli, awọn miran li apa ihin, awọn miran li apa ọhún: nwọn si pa wọn, bẹ̃ni nwọn kò si jẹ ki ọkan ki o kù tabi ki o sálọ ninu wọn.

Joṣ 8

Joṣ 8:20-30