Yorùbá Bibeli

Joṣ 8:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ti o ba si dide kánkan kuro ni ipò wọn, bi o si ti nàwọ́ rẹ̀, nwọn sare, nwọn si wọ̀ ilu na lọ, nwọn si gbà a; nwọn si yára tinabọ ilu na.

Joṣ 8

Joṣ 8:15-21