Yorùbá Bibeli

Joṣ 6:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati Joṣua wi fun awọn enia tán, awọn alufa meje ti o gbé ipè jubeli meje, kọja niwaju OLUWA nwọn si fọn ipè wọnni: apoti majẹmu OLUWA si tẹle wọn.

Joṣ 6

Joṣ 6:5-11