Yorùbá Bibeli

Joṣ 6:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joṣua si gbà Rahabu panṣaga là, ati ara ile baba rẹ̀, ati ohun gbogbo ti o ní; o si joko lãrin Israeli titi di oni-oloni; nitoriti o pa awọn onṣẹ mọ́ ti Joṣua rán lọ ṣamí Jeriko.

Joṣ 6

Joṣ 6:18-27