Yorùbá Bibeli

Joṣ 5:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati nwọn kọ gbogbo awọn enia na nilà tán, nwọn joko ni ipò wọn ni ibudó, titi ara wọn fi dá.

Joṣ 5

Joṣ 5:4-13