Yorùbá Bibeli

Joṣ 4:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joṣua si wi fun wọn pe, Ẹ kọja lọ niwaju apoti OLUWA Ọlọrun nyin si ãrin Jordani, ki olukuluku ninu nyin ki o gbé okuta kọkan lé ejika rẹ̀, gẹgẹ bi iye ẹ̀ya awọn ọmọ Israeli:

Joṣ 4

Joṣ 4:1-13