Yorùbá Bibeli

Joṣ 4:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Reubeni, ati awọn ọmọ Gadi, ati àbọ ẹ̀ya Manasse, si rekọja ni ihamọra niwaju awọn ọmọ Israeli, gẹgẹ bi Mose ti sọ fun wọn:

Joṣ 4

Joṣ 4:5-22