Yorùbá Bibeli

Joṣ 3:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn alufa ti o rù apoti majẹmu OLUWA, si duro ṣinṣin lori ilẹ gbigbẹ lãrin Jordani, ati gbogbo awọn enia Israeli kọja lori ilẹ gbigbẹ, titi gbogbo awọn enia na fi gòke Jordani tán.

Joṣ 3

Joṣ 3:9-17