Yorùbá Bibeli

Joṣ 3:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe, lojukanna bi atẹlẹsẹ̀ awọn alufa ti o rù apoti OLUWA, Oluwa gbogbo aiye, ba ti tẹ̀ omi Jordani, omi Jordani yio ke kuro, ani omi ti nti òke ṣànwá; yio si duro bi òkiti kan.

Joṣ 3

Joṣ 3:7-17