Yorùbá Bibeli

Joṣ 24:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn kigbepè OLUWA, o fi òkunkun si agbedemeji ẹnyin ati awọn ara Egipti, o si mú okun ya lù wọn, o si bò wọn mọlẹ; oju nyin si ti ri ohun ti mo ṣe ni Egipti: ẹnyin si gbé inu aginjù li ọjọ́ pipọ̀.

Joṣ 24

Joṣ 24:3-11