Yorùbá Bibeli

Joṣ 24:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Israeli si sìn OLUWA ni gbogbo ọjọ́ Joṣua, ati ni gbogbo ọjọ́ awọn àgba ti o wà lẹhin Joṣua, ti o si mọ̀ gbogbo iṣẹ OLUWA, ti o ṣe fun Israeli.

Joṣ 24

Joṣ 24:26-33