Yorùbá Bibeli

Joṣ 24:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joṣua si kọ ọ̀rọ wọnyi sinu iwé ofin Ọlọrun, o si mú okuta nla kan, o si gbé e kà ibẹ̀ labẹ igi-oaku kan, ti o wà ni ibi-mimọ́ OLUWA.

Joṣ 24

Joṣ 24:20-33