Yorùbá Bibeli

Joṣ 23:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joṣua si pè gbogbo Israeli, ati awọn àgba wọn, ati awọn olori wọn, ati awọn onidajọ wọn, ati awọn ijoye wọn, o si wi fun wọn pe, Emi di arugbó tán, emi si pọ̀ li ọjọ́:

Joṣ 23

Joṣ 23:1-8