Yorùbá Bibeli

Joṣ 21:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ipín si yọ fun idile awọn ọmọ Kohati: ati awọn ọmọ Aaroni alufa, ti mbẹ ninu awọn ọmọ Lefi, fi keké gbà ilu mẹtala, lati inu ẹ̀ya Juda, ati lati inu ẹ̀ya Simeoni, ati lati inu ẹ̀ya Benjamini.

Joṣ 21

Joṣ 21:1-14