Yorùbá Bibeli

Joṣ 21:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati lati inu ẹ̀ya Naftali, Kedeṣi ni Galili pẹlu àgbegbe rẹ̀, ilu àbo fun apania; ati Hammotu-dori pẹlu àgbegbe rẹ̀, ati Kartani pẹlu àgbegbe rẹ̀; ilu mẹta.

Joṣ 21

Joṣ 21:25-35